LyricFind Logo
LyricFind Logo
Profile image icon
Lyric cover art

EXORCISM

Apple Music logo
Deezer logo
Spotify logo
Lyrics
Gbogbo ara kíkì apá-ún t'ójú rí ẹnu kò lè sọ
Adé ẹgùn jókòó lórí mi, èmi l'ọba jìyà jìyà
Egbo adá jiná ló mú mi tiro
Òun jà mí l'ọ̀rẹ́ òun ti ní kí yé s'òkun òó

Exorcism Exorcism kò má jáde, kò má jáde òó
Ó máa ń ṣe jẹ every season, lé wọn jáde, lé wọn jáde òó
Exorcism Exorcism lé wọn jáde, lé wọn jáde òó
Ó máa ń ṣe jẹ every season lé wọn b'ọ̀tá, lé wọn b'ọ̀tá

The other day i see a broda man bleeding in church oo
You're preaching hope to me but with a gunshot oo
A severed head not a cure to headache oo
Ta l'álẹ́jọ tó ń wọlé sọ ọ̀dẹ̀ mí
T'álò ń gb'ómijé ojú kàn'na
Ọ̀gẹ̀dẹ̀ bàjẹ́ è lọ̀ ọ̀ pọ́n ni
Páńsà ò fura páńsà ja

Exorcism Exorcism
Kò má jáde, kò má jáde òó
Ẹnu ṣe jẹ lọ́wúrọ̀
Kò má jáde, kò má jáde òó
Exorcism Exorcism kò má jáde, kò má jáde òó
Ó máa ń ṣe jẹ every season
Lé wọn b'ọ̀tá Lé wọn b'ọ̀tá

Just a likkle puff exhale and let it go
You let a demon inside obstruct your bloody flow
You're Sitting in a corner tryna pull a trigger on your medulla
Dúró náa, make I put your mama on the cellular
(Rage)
Rage eating me up like a cannibal
(Sage)
Sage me a burn it up send the devil out
Go tell the sun to tell the moon to align
Welcome to a bloody paradise

Exorcism Exorcism
Kò má jáde, kò má jáde òó
Ó máa ń ṣe jẹ every season
(Ah ah ah ah ah ah )
Kò má jáde, kò má jáde òó
(Jáde òó)
Exorcism, Exorcism
Kò má jáde, kò má jáde òó
Ojú ṣe'jẹ every season
(Ṣ'ẹ̀jẹ̀)
Lé wọn b'ọ̀tá, lé wọn b'ọ̀tá
Lé s'ígbó

WRITERS

Aluko Adewale

PUBLISHERS

Lyrics © O/B/O DistroKid

Share icon and text

Share


See A Problem With Something?

Lyrics

Other

LyricIQ Analysis

Top Emotion

Anger

Sentiment
Thumbsup Icon
Theme

Sexual