Olúrun Ọba ló lè ṣe ohun gbogbo lójoojúmọ́
Níbi gbogbo, nígbà gbogbo, níbi gbogbo
Amen is my response to prayer, oh
Amen is my response to prayer, oh
Ooh, oh-oh-oh, oh, oh, oh, oh, oh-oh-oh
Amen is my- (amen is my response to prayer, oh)
Amen is my- (amen is my response to prayer, oh), whoa-oh, oh
Amen is my- (amin ni ìdáhùn m'àdúrà)
Amin ni ìdáhùn (amin ni ìdáhùn m'àdúrà)
Amen is my- (amen is my response to prayer, oh)
Amen is my- (amen is my response to prayer, oh)
Amin ni ìdáhùn (amin ni ìdáhùn m'àdúrà)
Amin ni ìdáhùn (amin ni ìdáhùn m'àdúrà)
A new season has started, oh
I am wealthy, I am blessed
Ó ṣòro fún mi ní mọ̀ dájú
Níbi tí ẹgbẹ́ mi ti ń ná owó mi, òní náà jù níbẹ̀ o
A new season has started, oh
I am favored, I am blessed
Ó ṣòro fún mi ní mọ̀ dájú
Níbi tí ẹgbẹ́ mi ti ń ná owó mi, òní náà jù níbẹ̀ o
My days have been broke over, oh
I am wealthy, I am blessed
Ó ṣòro fún mi ní mọ̀ dájú
Níbi tí ẹgbẹ́ mi ti ń ná owó mi, òní náà jù níbẹ̀ o
Amin, amin, amin, amin (amin ni ìdáhùn àdúrà o)
Amin, amin, amin ashe (amin ni ìdáhùn àdúrà o)
Amin, amin, amin, amin (amin ni ìdáhùn àdúrà o)
Amin, amin, amin ashe (mi ò ní tọrọ jẹ láyé)
Amin, amin, amin, amin (mi ò ní ẹ̀rù ẹ̀yìn láyé mi, o ṣùre fún mi)
Amin, amin, amin ashe (ìpá mi ò ní pín)
Amin, amin, amin, amin (mi ò ní di olókìkí àná láyé mi o)
Amin, amin, amin ashe (amin lẹ́ẹ̀kan sí)
Amin, amin, amin ashe (jẹ́ àjọ ṣe àmín o)
Amin, amin, amin, amin (mi ò ní ẹ̀rù ẹ̀yìn láyé mi, o ṣùre fún mi)
Amin, amin, amin ashe (ìpá mi ò ní pín)
Amin, amin, amin, amin (mi ò ní di olókìkí àná láyé mi o)
Amin, amin, amin ashe (amin lẹ́ẹ̀kan sí)
This year, this year, a máa lówó lọ́wọ́ o (amin)
This year, nínú ọdún yìí o, a máa bí ọmọ lẹ́mọ o (amin)
Gbogbo ẹni tó ń wo ojú Olórun fún ọmọ, fún wọn l'ọ́mọ o (amin)
Gbogbo ẹni tó ń wo ojú Olórun fún ọkọ, fún wọn l'ọ́kọ tíwọn o (amin)
Gbogbo ẹni tó ń wo ojú Olórun fún aya, fún wọn l'áya o (amin)
Gbogbo ẹni tó ń wo ojú Olórun fún ilé kíkọ́, dá wọn lóhùn o (amin)
Gbogbo ẹni tó ń sunkún ìkọ̀kọ̀, ẹkún yẹn dópin lónìí o (amin)
Ìwọ tí a ti rò pé ó pin, wá di èèyàn láyé rẹ o (amin)
Ẹni bá bá àìsàn fínra, kó mú ara dá (amin)
Ìwọ tí a ti rò pé ó pin, ìgbé dìde ti dé o (amin)
Àwọn tó ń wọ́mọ, ó ti dé o (amin)
For everyone battling depression o, gbọ́ àdúrà wọn o (amin)
Gbogbo wa tí a ń ṣiṣẹ́ o, pín wa l'èrè lójoojúmọ́ o (amin)
Gbogbo ẹni tó ń sunkún ìkọ̀kọ̀, ẹkún yẹn dópin lónìí o (amin)
Ìwọ tí a ti rò pé ó pin, wá jẹ́ èèyàn láyé rẹ o (amin)
Ẹni bá ń fi àìsàn fínra, a mú ẹ lára dá o (amin)
Ẹni a ti pè ní ẹ̀rù ẹ̀yìn, a sún wọn sí iwájú (amin)
Ẹni ayé ti tì o, lọ́dún yìí a tún wọn lọ́wọ́ kọ́ o (amin)
Ẹni ayé ti yọ o, wọ́n tún ìtàn ẹ kọ o (amin)
Ẹni a pè ní òfò o, ó di ológo o (amin)
Àní ẹni a pè ní òfò o, ó di ológo o (amin)
Ẹni a pè ní ọ̀lẹ o, ó gba agbára o (amin)
Ẹni a ti pè ní ọ̀lẹ o, ó gba agbára o (amin)
Ẹni a ti pè ní ọ̀lẹ o, ó gba agbára o (amin)
Ẹni ayé ti bù o, a tún ìtàn ẹ kọ o (amin)
Amin, amin, amin ashe (mi ò ní tọrọ jẹ láyé)
Amin, amin, amin ashe (imọ́lẹ̀ ńlá ló tàn)
Amin, amin, amin, amin (fool me) (imọ́lẹ̀ ńlá ló tàn bá mi ṣe amin o)
Amin, amin, amin ashe (imọ́lẹ̀ ńlá ló tàn)
Amin, amin, amin, amin (sórí mi, sórí ẹ̀bùn mi)