LyricFind Logo
LyricFind Logo
Profile image icon
Lyric cover art

Oro

Apple Music logo
Deezer logo
Spotify logo
Lyrics
Hum hum soro amuse

Hum hum toba soro amuse

A soro matase
Boba ti soro a muse
O wibe se bee
Boba ti soro a muse

Hum hum (awimayehun) soro amuse (alewilese)
Hum hum to ba soro a muse

Alagbara lo’lorun
Olorun ti mo nsin
Toba soro a muse
Jesu alewilese

Alagbara lo’lorun
Olorun ti mo nsin
Toba soro a muse
Jesu alewilese

Kilohun to n mi e lokan
Kilohun to njae laya
Toti rope ko seese
O lagbara lati se

A see a yori
Toralasepe ni Baba
Sa ti gbagbo ninu re
Boba ti soro a muse

Alagbara lo’lorun
Olorun ti mo nsin
Toba soro a muse
Jesu alewilese

Oro kan lo so si Hannah
Tofi di’ya olo’mo
O soro si Sera
O diya orile ede

Baba soro saye mi
Kaye mi o nitumo
Baba soro saye mi o
Kaye mi o gbatunse

Alagbara lo’lorun
Olorun ti mo nsin
Toba soro a muse
Jesu alewilese

O ji oku Lasaru
Pelu agbara nla
O ji oku omo Jairu
Pelu agbara nla

O wo’binrin orisun eje san
Pelu agbara nla
O tun mo’mi jade ninu apata
Pelu agbara nla

O lana ni Jodani
Pelu agbara nla

Baba soro
Baba soro
Baba soro
Saye mi o

Baba soro, dakun soro, ko wa soro saye mi
Oro to so si Jabesi ta’ye re yipada sire

Baba soro, dakun soro ko wa soro saye mi
Oro to so saye Hannah to fi diya olomo

Baba soro, dakun soro ko wa soro saye mi
Oro to fagi kedari ya kowa fogun aye mi ya

Baba soro, dakun soro ko wa soro saye mi
Oro to wo alaarun egba kowa wo aye mi san

Baba soro, dakun soro ko wa soro saye mi

Baba soro
Baba soro
Baba soro
Saye mi o

Baba soro, dakun soro ko wa soro saye mi
Oro lofi da aye ato’run wa soro re saye mi

Baba soro, dakun soro ko wa soro saye mi
Iji gboro re o dake
Soro kiji aye mi pa lolo

Baba soro, dakun soro ko wa soro saye mi

Baba soro
Baba soro dakun soro s’ayemi

Baba soro, dakun soro ko wa soro saye mi
Baba soro jare soro, dakun soro saye mi

Baba soro, dakun soro, ko wa soro saye mi

WRITERS

Tope Alabi, Bakare Boluwatife Oluwatobi

PUBLISHERS

Lyrics © ATMR SONGS, ALLTRACK

Share icon and text

Share


See A Problem With Something?

Lyrics

Other