Asho oju Lagbaja (Asho oju Lagbaja)
Won ti lo fi ran pata (Won ti lo fi ran pata)
CD brother Nuru (CD brother Nuru)
Won ti fi gba guguru (Won ti fi gba guguru)
Shebi oun lo ma sha prapra
Credit alert lo ma gbo pan pan (Gbo pan pan)
Ewo lion to lon sa fun aja
Awon alakori lo ro ejo fun Lagbaja
Omo to ba calm down lo na gba bone straight
Eni feyin siwa lo ma gba Colgate
A ko ero won nu club won run kigbe no space
Awon iya mi l'oru o ma kin sanwo tollgate
Asho oju Lagbaja (Asho oju Lagbaja)
Won ti lo fi ran pata (Won ti lo fi ran pata)
CD brother Nuru (CD brother Nuru)
Won ti fi gba guguru (Won ti fi gba guguru)
CD brother Nuru lon ti fi gba fair fun won
Gucci perf won fe ra won lo ta lofinda fun won
Shebi e le mad ni a ni gba fun won
Awon to wa ishubo wa amin ashey ko ni da fun won
Gbe ori wo nu lamba sa fun bi okete
Ati mo yen tey tey idi wa leyin na ege
Ma fun mi ma wo be ma screenshot IBD Dende
Asho oju lagbaja (Asho oju Lagbaja)
Won ti lo fi ran pata (Won ti lo fi ran pata)
CD brother Nuru (CD brother Nuru)
Won ti fi gba guguru (Won ti fi gba guguru)