O la na fun awon omo Israeli
O la na fun awon omo Israeli
Oooooooo la na fun awon omo Isrealii
Alagbara to n' gba agbara l' owo alagbara
Owun lo l émi ti mo m' mi
Oba to ran wa lówo ni gba ti Aba si se
Owun l' Oba to Joko si ori ité Ni agbala awon eni
Bi oni ja ba l' owun Oja mó
Iwó a l' o sésé béré ti é
Oba ti n'gbe ni ibi ti akolegbe
Oba to ma wa nigba ti aye o ni si