You no fi block my way oh
Baba lóòkè má lọ sọ ẹ̀mí ò!
Èmi ìdòní gòngón, mi ò gbọ́ kònkòn!
Bullion Van fé fi kò owó lọ.
I dey face my fears, and me I know care
Look on God, baba lift my heads
And this life dé rì bá kòn
I’m a fit gangster fighting kung fu
An I put my life and soul on God
And me go vibes till kingdom come
Kílọ́ fẹ́ sọ̀, àní kí ló fẹ́ sọ̀
Wọ́n ti bẹ́bọ̀ wòlé rí kọ̀n kọ̀n
Fún mi rissler, bá mi wẹ̀ Cana
Ẹyin tó láyé, ẹ̀ dúró tì mí o
Kálànú mi, kówá mí rere o.
Ó ṣúre pé mo máà kọ́rẹ́dé, Baba bámi se
Máa só mí lọ, máa jẹ́rí dé n’ó