LyricFind Logo
LyricFind Logo
Profile image icon
Lyric cover art

B'aye Ba N Fa Mi

Apple Music logo
Deezer logo
Spotify logo
Lyrics
B'aye ba nfa mi pelu ogo re,
Ko s'ewu, omo Olorun ni mi,
Owo agbara Re yo di mi mu,
L'ojo aye mi gbogbo.

Mo l'ore t'O npese f'aini gbogbo,
Mo n'ile kan loke orun giga,
Wo! Nitori idi eyi na ni,
Emi se nko Aleluya!

Emi ko je gbagbe pe lor'igi,
Ni Omo Olprun gbe ku fun mi;
Ko le saiku lati gb'okan mi la,
Ko tun si ona miran.

Mo l'ore t'O npese f'aini gbogbo,
Mo n'ile kan loke orun giga,
Wo! Nitori idi eyi na ni,
Emi se nko Aleluya!

N o j'oloto s'Oluwa Oba mi,
N o ma korin 'yin si nigbagbogbo,
Mo mo pe nikehin; On yo gba mi;
Lati ma ba gbe titi.

Mo l'ore t'O npese f'aini gbogbo,
Mo n'ile kan loke orun giga,
Wo! Nitori idi eyi na ni,
Emi se nko Aleluya!

WRITERS

EMMANUEL EDUNJOBI

PUBLISHERS

Lyrics © TUNECORE INC, TuneCore Inc.

Share icon and text

Share


See A Problem With Something?

Lyrics

Other

LyricIQ Analysis

Top Emotion

Enjoyment

Sentiment
Thumbsup IconThumbsup IconThumbsup Icon
Theme

Sexual