O si j′oba lori orile-ede
Je ki won yin oruko re ti o tobi ti o si ni eru
E ni pe gbogbo aye n wariri
O si j′oba lori orile-ede
Je ki won yin oruko re ti o tobi ti o si ni eru
'Tori gbogbo aye n wariri
Ani gbogbo aye n wariri o
Awon oke nla nla won f′oribale
Ju oke nla ikogun won ni lo
To n gbe laarin awon Kerubu
T′o po ni ipa ati agbara o
E ti tobi to o (Ladies and gentlemen)
Jesu (Welcome Pelumi Deborah)
Awon orun n soro ogo Olorun
Oru de oru n fi imo han oooo
Ko si ibi kan tabi ede kan
N'ibi ti a ko ti gbo iro wan
E ti tobi to o (Jesu Jesu Jesu o)
Mo le ko gbogbo eyin mi si Inu apere re
Jodani ri o o pada s'eyin
E ti tobi to o (Apata Idigbolu)
Bibeli ni ti Oluwa ni ile ati ekun re
Aiye, ati awon ti o tedo si Inu re
Nitori ti o fi idi re sole lori okun
Tani yio gori oke Oluwa lo?
Tabi tani yio duro nibi mimo re?
Eniti o ni owo mimo ati aya funfun
Eniti ko gbe okan re ka′le soke si asan
Ati ododo l'owo Olorun igbala re
Eyi ni iran awon ti n se aferi re
Ti n se aferi re Olorun Jakobu
E gbe ori yin s′oke, eyin enu-ona
Ki a si gbe'yin s′oke, eyin ilekun ayeraye
Oluwa ti o le ti o l'agbara
Oluwa ti o l'agbara ni ogun
E gbe ori yin s′oke, eyin enu-ona
Ki a si gbe′yin s'oke, eyin ilekun ayeraye
Oluwa Olorun awon omo ogun
Oun na ni Oba ogo (Jeeeesu)
Ar′aye-r'orun leekan soso
E ti tobi to o (eeeeeeeeh)
See finish ko si l′oro re o
Oo gba′se l'owo enikeni ko to p'ase
Ta lo dabi ire ninu agbara
Iwo to ma n tun ori alaisuwon se
Irorun lo ba de l'odo re Oko mi
O da aye s′ori omi, omi o je gbe'le aye lo
Tani o to ri e tan Olorun majemu
Iranlowo eni ti o l′eyan, oko mi
Olorun ti o ki n rin irin idoti
Olorun ta o le fi iwosi re l'ara
E ba n gb′osuba f'ajunilo
E ba mi juba f'ajunilo (E ba mi o)
E ba n gb'osuba f′ajunilo
E ba mi juba f'ajunilo (See see see)
Let me teach you the Juba dance
E ba n gb′osuba f'ajunilo
E ba mi juba f'ajunilo (E ba mi e ba mi e ba mi)
E ba mi juba f′ajunilo (E ba n gb'osuba)
E ba n gb′osuba f'ajunilo (Awon agbagba)
E ba mi juba f'ajunilo (merinlelogun won n ju′ba)
Won n ju′ba (E maa ju'ba lo)
E ba mi juba f′ajunilo (E ba wa ju'ba e ba mi ba mi o)
E ba mi juba (Eh) f′ajunilo
Oba to n be lori ite titilai (E ba n gb'osuba f′ajunilo)
A da'ra po mo awon orun lati keee (E ba mi juba f'ajunilo)
E ba mi juba f′ajunilo (Si Oluwa Olorun Olodumare)
E ba mi juba f′ajunilo (A si ite wa le'le)
A si aye wa le′le (E ba n gb'osuba f′ajunilo)
A gbe s'ori ese re ooooo (E ba mi juba f′ajunilo)
E ba mi juba f′ajunilo (E ju'ba f′olojukan)
Ti n wo egbegberun eniyan (E ba n gb'osuba f′ajunilo)
E ju'ba f′oloruko ape ri iye ooo (E ba mi juba f'ajunilo)
E ba mi juba f'ajunilo (A ju′ba fun e Mogaji awon alagbara)
E ba mi juba f′ajunilo (A ju'ba re oba to n so egan d′ogo)
E ba n gb'osuba f′ajunilo
E ba mi juba f'ajunilo (Eh eh eh eh eh eeeeeh)
E ba mi juba f'ajunilo (Aju'nilo o)
E ba n gb′osuba f′ajunilo
E ba mi juba f′ajunilo (tori pe)
Ero mimo l′ona (O si je o)
Won n k'orin, (e ti tobi to o)
Somebody shout Hallelujah