T′o ra ọ pada kuro lowo iku
T′o n se idajo fun gbogbo awon
E yin Oluwa gbogb′eyin omo Rẹ o
Yin Oluwa gbogbo ise ọwọ Rẹ o
Nibi gbogbo ninu ijoba Rẹ o
Ẹ yin Oluwa gbogb'eyin omo Rẹ o
Ẹyin iranse Rẹ ti e nse ti ifẹ Rẹ
Yin Oluwa gbogbo ise ọwọ Rẹ o
Nibi gbogbo ninu ijoba Rẹ o
(Ọjọ aye ọmọ eniyan dabi ti koriko)
Jo s'otun s'osi (Eniyan a si ma gbile)
Tor′ola Re mbere orin mi (Sugbon bi afefe ba ti fẹ kọja lori re)
Ni gidigan se (A re danu)
Sugbọn titi aye ni ifẹ Oluwa ti kii yẹ
K′o k'orin ope (si awa ti o beru Rẹ)
Yin Oluwa Oluwa wa (Tor′ola Re mbere orin mi)
Ododo Rẹ kii yẹ (ni gidigan se)