Ninu Irinkerido mi laiye, hmm iwo lo bami se
Alubarika ti mo riri, emi ko, atodo olorun ni
ewu gbogbo ti mo la koja, ki ma i s’agbara mi
Atinuda, ti mo ni loje kin dupe ore
Ebenezeri wa re e o nibi te ran wa lowo de
K'amaa jo o, k’ayo, k’a f’ogo f'olu
Ebenezeri wa re e om e ma ma se e se
Ki ma i se nipa agbara oluwa lo ni imo at'oye
Ogo t’aiye ri t’on polongo, ire lo bawa se
Orin Halleluya, Hosana lo gbenu wa kan
Rest: A dupe oluwa, ibi t’ee mu wa lo
Bi koba si t’oluwa, to ti wa ni tiwa o
Ni bo la ba jasi o, amo ni sehin a dupe at’ope da
T’oripe, awon kan gbeke le keke,
Awa ta gbeke le o, ibi to muwa de re, ibi ogo ni, la se wipe
Orin haleluyah, Orin hosana o, Orin Ebenezer, Hosana lo gb’enu wa kan
Ebenezeri wa re e o nibi te ran wa lowo de
K'amaa jo o, k’ayo, k’a f’ogo f'olu
Ebenezeri wa re e om e ma ma se e se
Ki ma i se nipa agbara oluwa lo ni imo at'oye
Ogo t’aiye ri t’on polongo, ire lo bawa se
Orin Halleluya, Hosana lo gbenu wa kan
Agbo igbe ibukun aidiye le, to fi fun wa a a, la se ndupe
Agbo igbe ibukun aidiye le, to fi fun wa a a, la se ndupe
Ebenezeri wa re e o nibi te ran wa lowo de eh eh eh
K'amaa jo o, k’ayo, k’a f’ogo f'olu
Ebenezeri wa re e om e ma ma se e se
Ki ma i se nipa agbara oluwa lo ni imo at'oye
Ogo t’aiye ri t’on polongo, ire lo bawa se
Orin Halleluya, Hosana lo gbenu wa kan