Ijo abimi saye shay lonjo
Mo sunkun waye e, wo omo ounto pamilekun
Ewure towole tiko kago, molodi eran amuso
koseni towi funmi pogunlaye
Baami oraso debi toma kole ee
Won o jeko tegbe (Ogun niwa ogun leyin baami akano)
Oti e ni ijokan lanlordu de o
Kilode loba figbeta, Oni eban gbowo ile mi
Mama nke baba nke omo nwo komotunmo o
Iwo shamalo shamalo s'abule
Lofori pamon, tawa fimarile
Mama nke baba nke omo nwo komotunmo o
Amoke gbami towo tese o (Amoke Amoke Amoke)
Mojade iwe mewa, Moba dari seko
Ninu yarakan o, Awa bi mejila
Kope kojina baba fiwale lo
Kope kojina baami dagbere faye
Won wo sunsun se lon damiloro o
Tori emi malowo,malola majeniyan o