LyricFind Logo
LyricFind Logo
Profile image icon
Lyric cover art

Twinkle

Apple Music logo
Deezer logo
Spotify logo
Lyrics
It's Lagos Igbo boys
Oh, oh.
Mmm, mmm, mmm, mmm.mmmm,mmmm,mmm

Twinkle, twinkle, little star.
I dey wonder what you are.
cs you dey light my world so bright.

Mmm, mmm, mmm.
Twinkle, twinkle, little star
I dey wonder what you are
cs you dey light my world so bright
Tín bá n binu
Se o ma pamilerin
Make me smile, make me feel alright
Tín bá Sukun, yeah
Ṣó lọ má rè mi lẹ́kùn
Munu midun, fà mí mọ́ra tight

You make me hungry, hungry, hungry
Not for food, but for love
You make me hungry, hungry, hungry
Not for food, but for love

Mo ti reni kẹ́jì mi
Ẹ ní bi, ọkan mi
Tó fẹ́ mi lóju, Fẹ́ mi ní mu
Kẹ́ mi bi ẹyìn

Mo ti reni kẹ́jì mi
Ẹ ní bi, ọkan mi
Tó fẹ́ mi lóju, Fẹ́ mi ní mu
Kẹ́ mi bi ẹyìn

Ma a lọ kọ́ Kung Fu nítorí rẹ,
ma a lọ kọ́ Taekwondo nítorí rẹ
Kín ba lè wà pẹ̀lu rẹ
Mo lè pọkun sọ tori ẹ,
gba gbogbo lọan tori ẹ́
Kín ba lè wà pẹ̀lu rẹ
Sofi li genti, sofi li genti, lo shen femi , lo shen kemi,

You make me hungry, hungry, hungry,
Not for food, but for love
You make me hungry, hungry, hungry,
Not for food, but for love

Mo ti reni kẹ́jì mi
Ẹ ní bi, ọkan mi
Tó fẹ́ mi lóju, Fẹ́mi ní mu
Kẹ́mi bi ẹyìn

Mo ti reni kẹ́jì mi
Ẹ ní bi, ọkan mi
Tó fẹ́ mi lóju, Fẹ́mi ní mu
Kẹ́mi bi ẹyìn

PUBLISHERS

Lyrics © HIGHVIBES DIGITAL LLC

Share icon and text

Share


See A Problem With Something?

Lyrics

Other