I will always care for you. Oh, oh, oh oh
I will always pray for you
I will always care for you. Oh, oh, oh oh
I will always pray for you.
Response: Iya lalabaro ọmọ
Iya t'obirin nje lo ri omo ko kere
Oba l'oke edumare dakun s'anu awa obirin
Mama je k'adamu l'ori awon eso wa
Oyun oko omoge aso omidan d'arugbo
Abiyamo oke so awon obirin wa layo oo
Abiyayo ni iya mi resp voice
Iya rere ni iya mi resp voice
Ori dakun je o jeun omo resp voice
Edumare je o jeun omo resp voice
Resp: baba loke setoju awon omo won
baba loke gbadura fun awon omo won
Ki won ma te aso ika mole oo
Call: Toju mama re lasiko to si wa o
Resp: toju mama re lasiko to wa oo ......