O si j'oba lori gbogbo orile-ede
Je ki won yin oruko re ti o tobi ti o si l'eru
Gbogbo aye n wariri ni oruko re, won n korin
Won n f'oribale niwaju ite re, won so wi pe
Awon oke nla nla wo n foribale o
Tori iwo ni Ogo ati Ola ju oke nla ikogun wonni lo o
Iwo ti Olorun ji dide kuro ninu oku
Lati gba wa kuro ninu ibinu ti mbo o
Iwo Oluwa Olorun to n gbe laarin awon Kerubu
To po ni ipa ati agbara o eh
A ni gbogbo aye n wariri ni oruko re, won n korin
Won n f'oribale niwaju ite re (won so wi pe)
Ipekun ola, ipekun iye e ti tobi to
Ireti wa o, Eri wa o e ti tobi to
Itansan orun to mole roro roro roro e ti tobi to
E ti tobi to o (won Juba f'oba Ajunilo)
Jesu (won f'oribale f'oba ajunilo)
Jordani ri o o pada s'eyin
Okun ri o o sa, e ti tobi to olodumare
Ab'etiluk'ara bi ajere, baba mi agba oye, e ti tobi to
Tori na, gbogbo aye n wariri ni oruko re, won n korin
Awon orun n s'eleri, won n f'ori ba'le niwaju ite re
Okan mi f'ori ba'le o, o so wipe
Ipekun ola, Ipekun oro, Ipekun agbara o eti tobi to
Ola ati ola nla ni owa ni iwaju re
Ipa ati ewa mbe ninu ibi mimo re o
Akaikatan o, Abuubutan o, atobiloye
Egbe leyin eni andaloro o eti eti eti tobi to
Jesu, gbogbo aye n wariri ni oruko re, won n korin
Awon orun na n s'eleri, won n f'oribale niwaju ite re o eh
E ba n gb'osuba f'ajunilo
(E ba mi Juba f'ajunilo) Ajunilo Jesu
(E ba n gb'osuba f'ajunilo) Ajunilo
(E ba n gb'osuba f'ajunilo) Ajunilo
(E ba n gb'osuba f'ajunilo) Ajunilo
(E ba mi Juba f'ajunilo) gbogbo aye n se'ba
(E ba mi Juba f'ajunilo) awon orun wo n foribale
(E ba mi Juba f'ajunilo) f'ajunilo
(E ba mi Juba f'ajunilo) Jesu
Gbogbo aye n wariri ni oruko re, won n korin