Ayílála nío gba pátá n'dí wọn
Ayílála nío gba pátá n'dí wọn
I cover myself with the blood and the "suu"
At the same time yío ba bábá nlá wọn
Everyday I'm stacking money bí Àyìndé Marshal ahh ah
Ìgbà tá sèsè bèrè they think say na wàsá
Gudu-Gudu méje laṣe kpèlú yàyà mèfá
Kòséní bínu omi gbà omi ò lòtá
Ó ngbóná feli feli pour me holy water ah ah!
Lòla Sati Ramoni lóke lóke nọni
Guiding pèlú prayer maami
Kíló kan ọmọ líle pelu what they say about me? Exactly!
Only money talk or ka páti
Show me where the money at I'm active
Lèyìn kàma ball bí Van Persie
Ìyaláyawọn gan nṣe dansaki
Ayílála nío gba pátá n'dí wọn
Ayílála nío gba pátá n'dí wọn
I cover myself with the blood and the "suu"
At the same time yío ba bábá nlá wọn
Everyday I'm stacking money bi Ayinde Marshal ahh ah