Ni'le aye 1980' something
Damilare emi l'akobi bami
Iya ati baba mi ti jaa o ti pe
Kin toh wa'ye loti ni won le fe'ra won
Okun ebi t'oba jaa welder kan o le jo alagbe
K'Olohun f'orun ke Moriamo iya baba mi
Mama o gbe mi sile k'eyan kan kan toju mi
Mi o gbagbe oko Alado l'ona Erugbabu
Oko obi yi Grandma ti foh loju kan
Boya n tori obi toh ma ta ni muri kan
Iya yi tun pada s'oko ada t'ohun t'oko ni
Ori mi a wu toh ba pe ni oko mi
Ojo ri je pelu ojo riri mu
Mama ma n r'oka pelu Efo Bokolu
L'abule Ado l'abule Ado oh abule Ado
Abule wa o jina si Shagamu
A n pada s'oko ni motor jam o ma shee
Mama ba n pariwo Damilare omolomo ni e ba n gbe
Ojo yen ni mo mo pe iya yi ko lo bi mi
Iya baba mi orun re e orun re e
Hmm ojo re bi ana nigba t'iku wole de
Iya yi ti r'iku loshey ni n b'ode na
Rafiu aburo mi n gba boolu nita
Mo wo'le pada mama ti d'oju bo'le
Kayeefi loje mo saare pe baba mi
Adio o wa dakun wa wo mama re
Ngba t'ariwo ta lowo mi n wa kilode
Shifau pelu Mutairu beree si nke omije oh
Won ni emi o jade tan ahh
Ojo 'keta Moria dagbere fun'aye
Iya baba mi orun re e orun re e Moriamo Moriamo oh
Odi'gba odi'gbere Moriamo
Moriamo omo Alege orun re e Moriamo
Ma ro'yin f'omo mi Moriamo oh
Moriamo Moriamo oh Moriamo
WRITERS
ABIODUN ADESHOLA BANJOKO, JUWONLO ILEDARE, OPEYEMI GBENGA KAYODE, QUDUS OLUWADAMILARE FAKOYA, TOLULOPE AJAYI