Sha ba la ba la ba la ba la ba
Sha ba la ba la ba la ba la ba, la ba la
Sha ba la ba la ba la ba la ba
I remember the last time last time
Tá won boys ti wo baggy that time
We no wan go school that time
Ta bá dè lo na because of break time
Á ó lo mu fan yogo sáyé wa
We no care if papa or mama dey for hard time
We been dey carry dreams everywhere
We been dey keep goals pass the care
I’m glad now we making it making it
At least some of us are making it
Owó lókè fún àwon pàdí mi lókè
E gbówó jáde e má lo pè mí lótè
Àni shó ti yáyá bebé n lo
Ati pé nísìhín kí là n dúró dè
E pà won eléré wá kó wá kógbòde
Àni shó ti yáyá bebé n lo
Pàdí mi róscó ìwo nìkan ni mo mò
Until tóbá fómo lóyún kó tó gbón (Kòmò)
You don get my backi o from my day one
Ìwo ni general wa ògá Gowon o
Before dem suo dance before alanta ye e
Na you dey use table drum for me then
Though my success story still dey for pending
You dey support me up till date (Torínáà)
Owó lókè fún àwon pàdí mi lókè
E gbówó jáde e má lo pè mí lótè
Àni shó ti yáyá bebé n lo
Ati pé nísìhín kí là n dúró dè
E pà won eléré wá kó wá kógbòde
Tó bá ti yáyá, e jé ká lo
Àni shó ti yáyá bebé n lo
Lágbára Oluwa a ò ní rèyìn (ah! bàmigbe)
Lágbára Oluwa a ò ní rèyìn
Owó lókè fún àwon pàdí mi lókè
E gbówó jáde e má lo pè mí lótè
Àni shó ti yáyá bebé n lo
Ati pé nísìhín kí là n dúró dè
E pà won eléré wá kó wá kógbòde
Àni shó ti yáyá bebé n lo
Johnson Ìgè is driving an Avalon
Musa n láwó epo ìyen ní Chevron
Benson Okafor dey ball for London
Àni shó ti yáyá e je ka lo
Lágbára Oluwa a ò ní rèyìn