LyricFind Logo
LyricFind Logo
Profile image icon
Lyric cover art

ASIKO (feat. LENNYKAY)

Apple Music logo
Deezer logo
Spotify logo
Lyrics
Tómòde ba n gegi ni igbó
Awòn agba agba lómo bi tó mi a wo sì
Éma sòró éyin
Laiyé ti mo wa
Mi o ni s'abòsi
Na we dae run town
NPG no fit run down
Pémi Lenny Boyyy, Oohh Goddda
I am back again, fire to the burn killer
Lie never
Èmi ófe tóro jè
Mó dárun móju ni, Lósu sè sè bébeé
Ngbá tao'dè wa bolà nle, ni mosè mó'omo ení ti mo n sè
Every hustler get a pay day
Am praying for one client to má mu mì upgrade
I no fit relent"cus" I must to survive
Aìmó asíko lo n daamu èda oo
Óró mi lówò olúwa lówa
Òró emi ati éé
Kiló n sò, kiló n sò
Òró wa lo n sò
Them no fit reason me anyhow
Owo lo gbé mi wa lagos
Make oju óta no go fit see us
All my guys inna convoy
Aìmó asíko lo n daamu èda oo oo
Òró mi lówò olúwa lówa
Òró mi lówò olúwa lówa
I've been focusing on the game
Chasing my dream
Been on the lane
Working for my fame
No matter what they say, nothing's stopping
Eyes on the price
That is my routine
No looking back, yeah"Cus" I believe me I go make it
Every blessings, every breath that I take
Every victory came by your grace
Òmó òlópe jà'iye ló
Pèlu plenty dolaporr
Aìmó asíko lo n daamu èda oo
Òró mi lówò olúwa lówa
Òró emi ati éé
Aìmó asíko lo n daamu èda oo oo
Òró mi lówò olúwa lówa
Òró mi lówò olúwa lówa
Òró mi lówò olúwa lówa
Kiló n sò, kiló n sò
Òró wa lo n sò
Ngbá tao'dè wa bolà nle
Ni mosè mó'omo ení ti mo n sè
Every hustler get a pay day
Am praying for one client to má mu mì upgrade
Hmm hmmmmm hmm hmmm hmmm hmmm hmm

WRITERS

Akinade Opeyemi

PUBLISHERS

Lyrics © O/B/O DistroKid

Share icon and text

Share


See A Problem With Something?

Lyrics

Other

LyricIQ Analysis

Top Emotion

Enjoyment

Sentiment
Thumbsup IconThumbsup Icon
Theme

Abuse and Violence