Oluwa sign soro me o (oluwa sign soro me o)
Oluwa dakun se temi funmi
Oluwa gbo adura me o (Oluwa gbo adura me o)
Oluwa bless hustle me o (Oluwa bless hustle me)
Oluwa dakun maje n lo lofo
Igba wo ni ire ma kan me o (Igba wo ni ire ma kan me o)
Oh oh oh baba ti ba mi se
Oni ki n ma lo, ki n ma lo , ki n ma lo
Ki n lo ma jubilate, yea yea
Oni ki n ma lo, ki n ma lo , ki n ma lo
Ki n lo ma celebrate, yea yea
Ko si ewu funwa, omo Olorun lawa
E o le deru bawa, ojojumo lo fi n gbo Adura wa
Ko si ewu funwa, omo Olorun lawa
E o le deru bawa, ojojumo lo fi n gbo Adura wa
Aiymoye pains ti mo go thru
Aiymoye dreams ti mo chase ti ko come true
Aiymoye emi nigg a se to de ti sonu
Base on say won fe pa owo yi se won de fe hustle
Mo bere orin kiko layi si eni to mo mi
Aiymoye rapper battle to ti mono to je pe omomi
Ere lo pe abi woh no be small story (small story)
Sugbon today me i give God the big glory (the glory)
Aiymoye oro werray to ti so leyin me
Sugbon nisiyin wo so pe awon fe feature me
Elo lo wa nle won so pe no money
Ti o ba ti si ooo wa ma lole bye bye
Kos sewu fun omo olorun lawa
Ojo jumo lo n fi gbo adura wa
Baba ti ba mi se (bami se)
Oni ki n ma lo, ki n ma lo , ki n ma lo
Ki n lo ma jubilate, yea yea
Baba ti ba mi se (bami se)
Oni ki n ma lo, ki n ma lo , ki n ma lo
Ki n lo ma celebrate, yea yea
Baba lo ni ki n ma lo...... eh
Owun lo ni ki n ma lo ....
Baba lo ni ki n ma lo ooo
Ki n somo lo, ki n gbomo lo