LyricFind Logo
LyricFind Logo
Profile image icon
Lyric cover art

Barrystar Vol. 1

•

2025

Eleduwa

Apple Music logo
Deezer logo
Spotify logo
Lyrics
(M—M—Murderer)
Ijọ buruku lo n'ijọ titun
Baba, ṣo n gbọ oun aiye n sọ?
Eleduwa, ẹyin l'akọkọ ninu gbogbo nnkan
T'ẹ to d'aiye at'ọrun
And that why me I put You first
In everything I do
O ma ma ṣe, Ọlọrun mi, o pọ, o pọ ọ
Ibi t'ọn ni ki gbe—gbe ma gbe lo fi ṣabale
Ibi t'ọn ni ki tẹtẹ ma tẹ lo lọ ṣe bar—k
Ngba t'ọn tun wa sọrọ, wọn ni mi mọ ju Ọlọrun lọ
Baba, ṣo n gbọ oun aiye n sọ?
Ayun lọ, ayun bọ l'ọmọ ẹyẹ n rin
Nkan o ni tabala mi l'ẹsẹ lọla Ọlọrun
L'atoni lọ ọna mi ko la peregede
L'atoni lọ, ma gbe orilẹ yii ṣe oun re—re
Ẹyin to laiye ẹ gb'ohun mi ṣ'aṣẹ pa
I be ọmọ aiye, ẹ duro ti mi, ki n ma ṣe jabọ o
Ikoko la fi ṣe, e gbọdọ fọ o
T'aiye ma fọ igba ikoko mi l'ẹnu
Ay, ti n ba lu ṣe ni ko ma dun
Ibi t'ọn ni ki gbe—gbe ma gbe lo fi ṣabale
Ibi t'ọn ni ki tẹtẹ ma tẹ lo lọ ṣe bar—k
Ngba t'ọn tun wa sọrọ, wọn ni mi mọ ju Ọlọrun lọ
Baba, ṣo n gbọ oun aiye n sọ?
Ayun lọ, ayun bọ l'ọmọ ẹyẹ n rin
Nkan o ni tabala mi l'ẹsẹ lọla Ọlọrun
L'atoni lọ ọna mi ko la peregede
L'atoni lọ, ma gbe orilẹ yii ṣe oun re—re
L'atoni lọ ọna mi ko la peregede
L'atoni lọ, ma gbe orilẹ yii ṣe oun re—re

WRITERS

ELIJAH OLANITE, OLUWAKAYODE BALOGUN

PUBLISHERS

Lyrics © Sentric Music, AFRO SOUNDTRACK

Share icon and text

Share


See A Problem With Something?

Lyrics

Other

More From This Album

Lyric cover art

Barrystar Vol. 1

2025

01

The Lord's Prayer

Barry Jhay

02

Eskelebebe

Barry Jhay

03

Do Not Disturb

Barry Jhay

04

Never Stop

Barry Jhay

05

Rest

Barry Jhay

06

Same Old Shit

Barry Jhay

07

Kilonso

Barry Jhay

08

Lost

Barry Jhay

09

See Me See God (SMSG)

Barry Jhay

10

What a Life

Barry Jhay

11

Eleduwa

Barry Jhay

From This Artist