LyricFind Logo
LyricFind Logo
Profile image icon
Lyric cover art

Jerimoyah

•

2024

Jerimoyah

Apple Music logo
Deezer logo
Spotify logo
Lyrics
Wur-uh-uh-uh-uh-uh-uh-uh
EE-Ee-ee-ee-ee
(?)
Wizka makun sko, oh-oh
Yeah-eh-eh-eh

Jerimoyah l'é
rimoyah l'èmèjè
(Train Wavy TK, mix it, baby)
Oh, Yeah-ay-ay-ay
Jerimoyah l'é, Jerimoyah l'èmèjè
Jerimoyah l'émèjè, aw-l'émèjè

Jerimoyah l'émèjè
Ọbá t'òn gb'èdè k'èdè
Ọbá tòh dári sànmón mèjè o
Ọbá tiò ma l'áfiwè

É jé á sòh itàn jànmó mèji
L'óbá ló s'ódó wòli
K'òlè d'ólá, k'òlè nìyi
Wòli s'óró f'ákókó

Wi pè òwò nbó wá fún
Sugbón láálá póju
F'òmó édá Adam
Wòli té siwáju ló

L'òbá s'óró fún ikèji
Wì pè á r'òwò òjijì
L'òbá kò ájè mèji
L'ówó awón jànmó mèji

Wì pè "é wì nté fé si
L'òwuró f'ójó mèjè
Sugbón ranti ènìkèji
Ọbá mi á má d'árá shá, rárá, kòs'éni bi

T'òbá d'èni, ò lè d'ólá, kò d'òdì fún ikèji
Ọbá mi á má d'árá

Òju áyè
Ò bá gbó nti time sóh
Wá mó pè kò s'áláyè
Ò nì ìbì t'èrè pór sunmó

Ni ikèji át'ákókó
Wòli má l'òn f'èdè fọh
Wì pè "kòsi anybody
Tá nkán t'Òluwá wì

Ákókó l'ólá pó ju,
Ò s'óró s'ájè pó ju
Ikèjí d'éri ípónju,
Ò p'òshé ju ájè sọn

Ilahi, Óbá yì
Má shèè wò mi
Ábiámọ t'òlójá yì
Mò d'èrò t'òri gáhin, Ilahi

Ọbá mi á má d'árá shá, rárá, kòs'éni bi (ye-ye)
T'òbá d'èni, ò lè d'ólá, kò d'òdì fún ikèji
Ọbá mi á má d'árá shá, rárá, kòs'éni bi
T'òbá d'èni, ò lè d'ólá, kò d'òdì fún ikèji

Ọbá mi á má d'árá shá, rárá, kòs'éni bi
Ò lè d'ólá
(Train Wavy TK, mix it, baby)
Kò d'òdì fún ikèji

WRITERS

Lawal Azeez Ajibola

PUBLISHERS

Lyrics © AFRO SOUNDTRACK

Share icon and text

Share


See A Problem With Something?

Lyrics

Other

More From This Album

Lyric cover art

Jerimoyah

2024

01

Jerimoyah

Wizka