Kapachimerimeripako santariteteruwa
Ọya when I wake up in the morning Spellz
Kinto gba débi Kinto gbà débi
When I wake up in the morning
Shebi adura momsi àti popsi mi
Shebi adura momsi àti popsi mi
Wọ them say love na one tin tin
Na so this ilé aiye sef gon bintin
A jo rin nígbà yẹn ni a'dẹ mọ ni olówó
Ti kpa ma fi àkara fún mẹ koko
Ki Jésù ranti wa ko ma j'awa ni kan ni nepa ma wa ja'na wà
Showers of blessing lẹ'npe
Tori every time t'ojo ba rọ o ma leak lati roof wa
And I wan build this legacy for my family
Before I komot for house I promise say them go be proud of me
Jésù nìkan mogbọ'kan le lẹyìn é kòsí ẹlomi
Lati ni iwọ pe Jesu ni mo pe to dẹ pick call mí
When I wake up in the morning
Kinto ba debi kinto ba debi
When I wake up in the morning
Kinto ba debi kinto ba debi ha wo
Shebi adura momsi àti popsi mi
Shebi adura momsi àti popsi mi
E ni binu e so fu pe ologo ni ko filẹ
Ki ma bọ kọ ni rara ko ki sho'un
Mọn ti fresh telé telé woni on shoun
Awọn l'abọsi awọn gbeborun